WEEK 2 DEETI ojoru_ ojo kewaa_ OSU erele_ odun 2011 KILAASI

					                         WEEK 2

DEETI:              ojoru, ojo kewaa, OSU erele, odun 2011

KILAASI:             JSS1

OJO ORI AKEKOO:          Omo odun mokanla

AKORI EKO:            Aroko atonisona oniroyin –akole, ilapa ero abbl

OHUN ELO IKONI:          kadiboodu ti a ko igbese aroko si

IMO ATEYINWA:           Awon akekoo le royin ohun to soju won

IWE ITOKASI:      Simplified Yoruba L1 for the basic education certificate examination
(basic 8). S. y Adewoyin 2009.

ERONGBA:     Ni opin idanilekoo yii, akekoo yoo le:

 (I)    So ohun ti aroko oniroyin je.
 (II)   Salaye awon igbese ti agbodo tele ti a ba n ko aroko
 (III)   Se apeere aroo oniroyin
 (IV)   Ko aroko oniroyin

                        AKOONU

Aroko oniroyin da lori riroyin isele to soju eni gan an tabi ti a fi oju ara wa ri. Eyi fi han pe bi a oo
ba ko aroko oniroyin lori koko-oro kan,o ye ki a ti ri ohun ti a n se iroyin re,ki iroyin ti a fe se le
rorun fun wa. Awon igbese ti a gbodo tele ti a ba n ko aroko.

        (I)   Ori – oro
        (II)   Ilapa – ero
  (a)  Ifaara
  (b)  Koko
  (c)  Ikadii
  (d)  Ogidi Yoruba
     Apeere aroko oniroyin:
     (i)    Ibewo emi ati ore mi si ogba eranko ti fasiti OAU.
     (ii)    Iroyin odun eyo ti o waye ni ilu Eko
     (iii)   Irinajo emi ati ebi mi si ilu oyinbo
     (iv)    Ayeye ayajo ominira ti o koja o
     (v)    Ere boolu afesegba kan ti mo wo
     (vi)   Ayeye ojo ibi mi ti o koja
                       Ayeye ojo ibi mi ti o koja

     (i)    Ojo ati akoko ti ayeye naa waye
     (ii)   Imurasile saaju ojo naa
     (iii)   Apejuwe ni ijo jijo se bere,bi won se nawo loju agbo ati ebun
     (iv)   Akoko jije mimu
     (v)    Ikadii:ero re lori ayeye naa

                        IGBEKALE

IGBESE I: Oluko yoo bere idanilekoo pelu imo ateyinwa.

IGBESE II: Salaye akori oro.

IGBESEIII: Fun won ni apeere aroko oniroyin lorisirisi.

IGBESE IV: Ni ki awon akekoo gbiyanju lati se apeere aroko oniroyin .

IGBESE V: Se apeere ilapa ero akori aroko oniroyin kan.
                       IGBELEWON

Kini igbese ti o ro mo aroko oniroyin.

                        ISE –SISE

Ko aroko ti ko ju lgba (200) lori akole yi: igba ojo.

IFIYESI/ISOROSI

--------------------

OLUDARI EKO
DEETI:         Ojoru,ojo keji,osu Erele,odun 2011

KILAASI:        JS 1

AKORI EKO:        Oge sise ni ile yoruba   - (ose keji eko)

IMO ATEYINWA: Awon akekoo mo nipa oge sise ti aye ode oni.

IWE ITOKASI: Imo ede ati asa,litireso Yoruba fun ile eko sekondiri agba ss1, lati owo Adewoyin
S.Y.

ERONGBA: Ni opin idanilekoo yii, akekoo yoo le:

 (I)    Daruko awon ohun ti a fi n s’oge ni ile yoruba
 (II)   Daruko awon ona ti a fi n soge
 (III)   Daruko ohun ti awon obinrin fi n soge ni ile Yoruba
 (IV)   Daruko ohun ti awon okunrin fi n soge ni ile yoruba

      AKIYESI PATAKI!

             ITESIWAJU LORI AKORI EKO YI LATI OSE TO KOJAIFIYESI/ISOROSI

--------------------

OLUDARI EKO
DEETI:         ojo isegun, ojo kejo,osu erele,odun 2011

KILAASI:        JSS2

OJO ORI AKEKOO:     Omo odun mejila

AKORI EKO:       Asa iranra-eni-lowo (owe, aaro)

OHUN ELO IKONI:     Aworan awon to n sise papo

IMO ATEYINWA:      Awon akekoo ni oye die nipa aaro, won si ti be eniyan ni owe ri

IWE ITOKASI:      Imo, Ede, asa ati litireso Yoruba fun ile eko sekondiri agba ss1. S.y
Adewoyin

ERONGBA: Ni opin idanilekoo yii, akekoo yoo le:

(I) so ohun ti owe je

(II) Salaye ohun ti aaro je

(III) Salaye ohun ti asa iranra eni lowo je
                       AKOONU

                        OWE

Owe ni bibe opo eniyan bii ebi,ore, tabi ojulumo lati ba ni sise nla bii ile kiko,ise oko yala ti eni
tabi ana eni. Eni ti o be owe gbodo pese ounje ati nnkan mimu fun awon eniyan to be lowe. Ki I
se dandan ni ki a san owe yi pada.

                        AAROAwon omodekunrin ti won ba je ore ti oko won wa ni itosi ara maa n be ara ni aaro fun ise oko
ti o ba papo. Gbogbo won yoo pawopo se ise naa ni ojo kan. Bi won ba ti n se ise eni kan tan ni
won yoo lo se ti enikeji titi ti won yoo fi se ise naa kari. Ounje ki I se dandan. Eni ti o ni aaro le
wa nnkan jiji ati mimu tabi ki oni kaluku seto ounje funra re.
IGBESE I:     Bere pelu imo ateyinwa.

IGBESE II:     Oluko yoo salaye ohun ti owe je.

IGBESEIII:     Awon akekoo yoo maa fi eti sile si alaye oluko.

IGBESE IV:     Oluko yoo salaye ohun ti aaro je.

IGBESE V:     Awon akekoo yoo maa fi eti sile.

IGBESE Vi:     Oluko yoo pe awon akekoo lati fi won se apeere aaro ati owe.
                       IGBELEWON

                   Salaye owe ati aaro ni ranpe

IFIYESI/ISOROSI

--------------------

OLUDARI EKO
DEETI:          Ojobo, OSU Erele, odun 2011

KILAASI:             JSS 2

OJO ORI AKEKOO:         Omo odun mejila

AKOKO:              keji ninu ose

AKORI EKO:            Iwe kika: odun A yako

IMO ATEYINWA:          Awon akekoo ti kaa iwe yi lati ibeere titi de ori keji

IWE ITOKASI:       Odun a yako? Lati owo Nikee Adesanya.sumob publishers.2007

ERONGBA: Ni opin idanilekoo yii, akekoo yoo le:

 (I) Salaye ori keji ati iketa

(II) Salaye awon oro to ta koko

(III) Dahun ibeere

                         AKOONU

                      Ori keji ati iketa

Awon oro to ta koko

Awon owe ti a ba pade.

                         IGBEKALE

IGBESE I:    Oluko yoo salaye ori kinni ati ikeji ni ranpe

IGBESE II:   Oluko yoo maa ka iwe naa si eti awon akekoo pelu alaye

IGBESEIII:   Awon akekoo yoo maa fi eti sile si iwe kika ati alaye oluko.

IGBESE IV:   Oluko yoo salaye awon owe ati oro to ta koko ti a ba pade

IGBESE V:    Awon akekoo yoo maa fi eti sile.

IGBESE VI:   fi aye sile fun ibeere

                 IGBELEWON

                 Salaye ori keji ati iketa ni ranpe
IFIYESI/ISOROSI

--------------------

OLUDARI EKO
DEETI:         ojo aje, ojo keje,osu erele,odun 2011

KILAASI:        JSS3

OJO ORI AKEKOO:     metala

AKORI EKO:       AROKO LETA KIKO – AIGBEFE

OHUN ELO IKONI:     leta kiko

IMO ATEYINWA:      awon akekoo ti ko ni pa leta gbefe ri

IWE ITOKASI:      Simplified Yoruba L1 for the basic education certificate examination
(basic98). S. y Adewoyin 2009.

ERONGBA: Ni opin idanilekoo yii, akekoo yoo le:

 (I)    So ohun ti leta aigbefe je
 (II)   Salaye awon igbese ti o ro mo leta aigbefe
 (III)   Ko leta aigbefe

                       AKOONU
Leta aigbefe ni leta ti a ko si awon eniyan to wa ni ipo ase bii oga ile ise oba,ile ise adani, ile iwe
abbl

Igbese meje ni a ni lati tele bi a ba fe ko leta aigbefe. Awon ni wonyi:

    Kiko adiresi akoleta
    Kiko deeti (ojo,osu, ati odun ti a ko leta)
    Ipo eni ti a ko leta si
    Ikini ibere leta
    Akole leta
    Koko oro inu leta
    Ipari ati oruko akoleta                         IGBEKALE

IGBESE I: Bere pelu imo ateyinwa

IGBESE II:Salaye leta aigbefe

IGBESEIII: Salaye awon ilana to ro mo leta aigbefe

IGBESE IV: FI apeere leta aigbefe han

IGBESE V:Awon akekoo yoo maa ko leta aigbefe ti won

                 IGBELEWON

                 Salaye ilana ti o ro mo l eta aigbefe

                       ISE ASETILEWA

      Ko leta ti ko ju igba (200) oro si oga ile iwe yi lori ilosiwaju eto ounje ile iwe yi.

IFIYESI/ISOROSI

--------------------

OLUDARI EKO
DEETI:         Ojoru,ojo ,osu Erele,odun 2011

KILAASI:        Jss 3

AKORI EKO:       Akaye

IMO ATEYINWA:     Awon akekoo ti ka akaye ri

IWE ITOKASI:     Simplified Yoruba L1 for the basic education certificate examination
(basic98). S. y Adewoyin 2009.

ERONGBA:        Leyin akaye yi, awon akekoo,yoo le

  I.  Salaye eko oun ti ayoka naa ko
 II.  So itumo awon oro to ta koko
 III.  Dahun ibeere ti o tele
                         AKOONU
     Akaye inu iwe itokasi ni oju ewe kokan le logofa(121)

                      IGBEKALE

     IGBESE I: se atunyewo ranpe lori ise ose to koja
     IGBESE II: se tunse ise naa fun awon akekoo
     IGBESE III: ka ayoka naa si eti awon akekoo
     IGBESE IV: awon akekoo yoo maa fi eti sile,won yoo si maa dahun ibeere ti o tele ayoka
     naa.
                        IGBELEWON
     Salaye ayoka naa ni ranpe


                       ISE SISE

Dahun awon ibeere ti o tele ayoka naa (16-20)IFIYESI/ISOROSI

--------------------

OLUDARI EKO
DEETI:              Ojo aje,ojo keje,osu erele,odun 2011

KILAASI:             SS1

OJO ORI AKEKOO:         Omo odun merinla

AKORI EKO:            Atunyewo awon isori oro oruko,oro asopo, abbl (ose meji)

OHUN ELO IKONI:         kaadi to ni awon isori oro

IMO ATEYINWA:          Awon akekoo maa n lo awon isori oro ninu awon oro won.

IWE ITOKASI: Imo, Ede, asa ati litireso Yoruba fun ile eko sekondiri agba SS1. S.y Adewoyinu

ERONGBA: Ni opin idanilekoo yii, akekoo yoo le:

 (I)    Daruko awon isori oro
 (II)   Se apeere awon isori oro
 (III)   Seda awon oro pelu isori oro lorisirisi
 (IV)   So ipa ti oluwa,eyan,abo n ko ninu gbolohun

                      AKIYESI PATAKI!

               ITESIWAJU LORI AKORI EKO TI OSE TO KOJAIFIYESI/ISOROSI

--------------------

OLUDARI EKO

				
DOCUMENT INFO
Shared By:
Categories:
Tags:
Stats:
views:91
posted:3/23/2013
language:Unknown
pages:11